Àwọn Ọba Kinni 4:23 BIBELI MIMỌ (BM)

àbọ́pa mààlúù mẹ́wàá, ogún mààlúù tí wọn ń dà ninu pápá, ati ọgọrun-un aguntan; láìka àgbọ̀nrín, egbin, ìgalà, ati oríṣìíríṣìí ẹyẹ àbọ́pa.

Àwọn Ọba Kinni 4

Àwọn Ọba Kinni 4:22-29