Àwọn Ọba Kinni 4:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Solomoni jọba gbogbo ilẹ̀ Israẹli,

2. Orúkọ àwọn olórí ninu àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ nìwọ̀nyí: Asaraya, ọmọ Sadoku ni alufaa.

Àwọn Ọba Kinni 4