Àwọn Ọba Kinni 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu bi àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ pé, “Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé àwa ni a ni ìlú Ramoti Gileadi? A kò sì ṣe ohunkohun láti gbà á pada lọ́wọ́ ọba Siria.”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:1-10