Àwọn Ọba Kinni 22:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mikaaya bá dáhùn pé, “Mo rí àwọn ọmọ ogun Israẹli tí wọ́n fọ́n káàkiri gbogbo orí òkè, bí aguntan tí kò ní olùṣọ́. OLUWA sì wí pé, ‘Àwọn eniyan wọnyi kò ní olórí, kí olukuluku wọn pada lọ sí ilé ní alaafia.’ ”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:7-27