Àwọn Ọba Kinni 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀dọ́ ọmọ ogun ni wọ́n ṣáájú ogun Israẹli, wọ́n bá lọ ṣígun bá Benhadadi. Àwọn amí tí ọba Benhadadi rán jáde lọ ròyìn fún un pé, àwọn eniyan kan ń jáde bọ̀ láti ìlú Samaria.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:13-23