Àwọn Ọba Kinni 18:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ́, ní ọdún kẹta tí ọ̀dá ti dá, OLUWA sọ fún Elija pé, “Lọ fi ara rẹ han Ahabu ọba, n óo sì rọ̀jò sórí ilẹ̀.”

2. Elija bá lọ fi ara han Ahabu.Ìyàn tí ó mú ní ìlú Samaria pọ̀ pupọ.

3. Ahabu pe Ọbadaya, tí ó jẹ́ alabojuto ààfin. Ọbadaya jẹ́ ẹni tí ó bẹ̀rù OLUWA gan-an.

Àwọn Ọba Kinni 18