Àwọn Ọba Kinni 15:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Baaṣa, ọmọ Ahija, láti inú ẹ̀yà Isakari, ṣọ̀tẹ̀ sí Nadabu, ó sì pa á ní ìlú Gibetoni, ní ilẹ̀ Filistia, nígbà tí Nadabu ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti ìlú náà.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:22-34