Àwọn Ọba Kinni 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mú burẹdi mẹ́wàá, àkàrà dídùn díẹ̀, ati ìgò oyin kan lọ́wọ́ fún un, yóo sì sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí ọmọ náà fún ọ.”

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:1-5