Àwọn Ọba Kinni 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ajá ni yóo jẹ òkú ẹnikẹ́ni ninu ìdílé rẹ tí ó bá kú láàrin ìlú; ẹni tí ó bá sì kú sinu igbó, ẹyẹ ni yóo jẹ òkú rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA wí.” ’

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:1-17