Àwọn Ọba Kinni 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wolii náà dáhùn pé, “Bí o bá tilẹ̀ fẹ́ fún mi ní ìdajì ohun tí o ní, n kò ní bá ọ lọ, n kò ní fi ẹnu kan nǹkankan ní ilẹ̀ yìí.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:3-13