Àwọn Ọba Kinni 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ pẹpẹ ìrúbọ kan sí orí òkè ní ìhà ìlà oòrùn Jerusalẹmu fún oriṣa Kemoṣi, ohun ìríra tí àwọn ará Moabu ń bọ, ati fún oriṣa Moleki, ohun ìríra tí àwọn ará Amoni ń bọ.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:4-17