Àwọn Ọba Keji 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sáré tẹ̀lé Naamani. Nígbà tí Naamani rí i pé ẹnìkan ń sáré bọ̀, ó sọ̀kalẹ̀ lórí kẹ̀kẹ́ ogun tí ó gùn láti pàdé rẹ̀, ó bèèrè pé, “Ṣé kò sí nǹkan?”

Àwọn Ọba Keji 5

Àwọn Ọba Keji 5:16-27