Àwọn Ọba Keji 4:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lọ fi ọ̀pá Eliṣa lé ọmọ náà lójú, ṣugbọn ọmọ náà kò jí. Ó bá pada lọ sọ fún Eliṣa pé ọmọ náà kò jí.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:21-32