Àwọn Ọba Keji 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan kékeré ni èyí jẹ́ níwájú OLUWA, yóo fun yín ní agbára láti borí àwọn ará Moabu.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:14-25