Àwọn Ọba Keji 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa bá dáhùn pé, “Bí OLUWA àwọn ọmọ ogun, ẹni tí mò ń sìn ṣe wà láàyè, n kì bá tí dá ọ lóhùn bí kò bá sí ti Jehoṣafati, ọba Juda, tí ó bá ọ wá.”

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:4-20