Àwọn Ọba Keji 17:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣe oríṣìíríṣìí nǹkan níkọ̀kọ̀, tí OLUWA Ọlọrun wọn kò fẹ́. Wọ́n kọ́ àwọn pẹpẹ ìrúbọ sinu àwọn ìlú wọn: wọ́n kọ́ sinu ilé ìṣọ́, títí kan àwọn ìlú olódi.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:1-19