Àwọn Ọba Keji 16:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasi kú, wọn sì sin òkú rẹ̀ sinu ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi, Hesekaya, ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:12-20