Àwọn Ọba Keji 13:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoaṣi ọba, ọmọ Jehoahasi, ṣẹgun Benhadadi ní ìgbà mẹta, ó sì gba àwọn ìlú tí wọ́n ti gbà ní ìgbà ayé Jehoahasi, baba rẹ̀ pada.

Àwọn Ọba Keji 13

Àwọn Ọba Keji 13:22-25