Àwọn Ọba Keji 10:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu kú, wọ́n sin òkú rẹ̀ sí Samaria, Jehoahasi ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:32-36