Àwọn Ọba Keji 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu ní aadọrin ọmọkunrin tí wọn ń gbé Samaria. Jehu kọ ìwé ranṣẹ sí àwọn olórí ìlú ati àwọn àgbààgbà ati àwọn olùtọ́jú àwọn ọmọ Ahabu, ó ní:

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:1-11