Àwọn Adájọ́ 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, àwọn ọmọ Israẹli wí fún Gideoni pé, “Máa jọba lórí wa, ìwọ ati ọmọ rẹ, ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ pẹlu, nítorí pé ìwọ ni o gbà wá lọ́wọ́ àwọn ará Midiani.”

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:16-28