Àwọn Adájọ́ 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, wọ́n gbàgbé OLUWA Ọlọrun wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bọ oriṣa Baali ati Aṣerotu.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:1-8