Àwọn Adájọ́ 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Samsoni pa ọpọlọpọ ninu wọn. Ó kúrò níbẹ̀, ó sì lọ ń gbé inú ihò àpáta kan tí ó wà ní Etamu.

Àwọn Adájọ́ 15

Àwọn Adájọ́ 15:1-11