Àwọn Adájọ́ 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbọ́ ohun tí èmi Jẹfuta wí, Israẹli kò gba ilẹ̀ kankan lọ́wọ́ àwọn ará Moabu tabi lọ́wọ́ àwọn ará Amoni.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:13-23