Àwọn Adájọ́ 10:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó jẹ́ aṣiwaju ní ilẹ̀ Israẹli fún ọdún mẹtalelogun, nígbà tí ó ṣaláìsí wọ́n sin ín sí Ṣamiri.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:1-7