Amosi 5:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí òkùnkùn ni ọjọ́ OLUWA, kì í ṣe ìmọ́lẹ̀! Ọjọ́ ìṣúdudu láìsí ìmọ́lẹ̀ ni.

Amosi 5

Amosi 5:17-27