Aisaya 63:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wò yíká, ṣugbọn kò sí olùrànlọ́wọ́,ẹnu yà mí pé, n kò rí ẹnìkan tí yóo gbé mi ró;nítorí náà, agbára mi ni mo fi ṣẹgun,ibinu mi ni ó sì gbé mi ró.

Aisaya 63

Aisaya 63:2-7