Aisaya 63:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọ́n hùwà ọlọ̀tẹ̀:wọ́n sì mú Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ bínú.Nítorí náà ó di ọ̀tá wọn,ó sì dojú ìjà kọ wọ́n.

Aisaya 63

Aisaya 63:1-17