Aisaya 62:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! OLUWA ti kéde títí dé òpin ayé.Ó ní, “Ẹ sọ fún àwọn ará Jerusalẹmu pé,‘Wò ó, olùgbàlà yín ti dé,èrè rẹ wà pẹlu rẹ̀,ẹ̀san rẹ sì wà níwájú rẹ̀.’ ”

Aisaya 62

Aisaya 62:9-12