Aisaya 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá bi í pé: “OLUWA mi, títí di ìgbà wo?”Ó sì dáhùn pé: “Títí tí àwọn ìlú yóo fi di ahoro, láìsí ẹni tí yóo máa gbé inú wọn; títí tí ilé yóo fi tú láì ku ẹnìkan, títí tí ilẹ̀ náà yóo fi di ahoro patapata.

Aisaya 6

Aisaya 6:5-13