Aisaya 59:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Wò ó! Agbára OLUWA kò dínkù, tí ó fi lè gbani là,etí rẹ̀ kò di, tí kò fi ní gbọ́.

2. Ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ yín ni ó fa ìyapa láàrin ẹ̀yin ati Ọlọrun yín,àìdára yín ni ó mú kí ó fojú pamọ́ fun yín,tí kò fi gbọ́ ẹ̀bẹ̀ yín.

Aisaya 59