Aisaya 57:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Olódodo ń ṣègbé,kò sí ẹni tí ó fi ọkàn sí i.A mú àwọn olótìítọ́ kúrò, kò sì sí ẹni tí ó yé,pé à ń yọ olódodo kúrò ninu ìdààmú ni.

Aisaya 57

Aisaya 57:1-7