Aisaya 54:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa kọrin! Ìwọ àgàn tí kò bímọ.Máa kọrin sókè, ìwọ tí kò rọbí rí.Nítorí ọmọ ẹni tí ọkọ ṣátì pọ̀,ju ọmọ ẹni tí ń gbé ilé ọkọ lọ,OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.

Aisaya 54

Aisaya 54:1-5