Aisaya 53:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wa ti ṣáko lọ bí aguntan,olukuluku wa yà sí ọ̀nà tirẹ̀,OLUWA sì ti kó ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa lé e lórí.

Aisaya 53

Aisaya 53:4-9