Aisaya 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí n kọrin kan fún olùfẹ́ mi,kí n kọrin nípa ọgbà àjàrà rẹ̀.Olùfẹ́ mi ní ọgbà àjàrà kanní orí òkè kan tí ilẹ̀ ibẹ̀ lọ́ràá.

Aisaya 5

Aisaya 5:1-9