Aisaya 45:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn eniyan lè mọ̀ pé, láti ìlà oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀,kò sí ẹlòmíràn lẹ́yìn mi.Èmi ni OLUWA, kò tún sí ẹlòmíràn.

Aisaya 45

Aisaya 45:3-10