Aisaya 45:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ yipada sí mi kí á gbà yín là,gbogbo ẹ̀yin òpin ayé.Nítorí èmi ni Ọlọrun,kò tún sí ẹlòmíràn mọ́.

Aisaya 45

Aisaya 45:16-25