Aisaya 45:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA gba Israẹli là,títí ayé sì ni ìgbàlà rẹ̀.Ojú kò ní tì ọ́, bẹ́ẹ̀ ni o kò ní dààmú, títí lae.

Aisaya 45

Aisaya 45:10-25