Aisaya 38:19-20 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Alààyè, àní alààyè, ni ó lè máa yìn ọ́bí mo ti yìn ọ́ lónìí.Baba a máa kọ́ àwọn ọmọ rẹ̀, nípa òdodo rẹ.

20. OLUWA yóo gbà mí là,a óo fi àwọn ohun èlò orin olókùn kọrin ninu ilé OLUWA,ní gbogbo ọjọ́ ayé wa.

Aisaya 38