Aisaya 38:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò náà, Hesekaya ṣàìsàn, àìsàn náà pọ̀; ó fẹ́rẹ̀ kú. Aisaya wolii, ọmọ Amosi tọ̀ ọ́ wá ní ọjọ́ kan, ó wí fún un pé: “OLUWA ní kí n sọ fún ọ pé kí o ṣe ètò ilé rẹ, nítorí pé o óo kú ni, o kò ní yè.”

2. Hesekaya bá kọjú sí ògiri, ó gbadura sí OLUWA,

Aisaya 38