Aisaya 36:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliakimu, ọmọ Hilikaya tí ó jẹ́ alákòóso ààfin jáde lọ bá wọn pẹlu Ṣebina, akọ̀wé ilé ẹjọ́, ati Joa ọmọ Asafu, akọ̀wé ààfin.

Aisaya 36

Aisaya 36:1-12