Aisaya 35:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Inú aṣálẹ̀ ati ilẹ̀ gbígbẹ yóo dùn,aṣálẹ̀ yóo yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, yóo rúwé, yóo sì tanná.