Aisaya 32:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dìde, ẹ̀yin obinrin tí ara rọ̀,ẹ gbóhùn mi; ẹ̀yin ọmọbinrin tí ẹ wà ninu ìdẹ̀ra,ẹ tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ mi.

Aisaya 32

Aisaya 32:8-19