Aisaya 32:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni nǹkan yóo rí,títí ẹ̀mí óo fi bà lé wa láti òkè ọ̀run wátítí aṣálẹ̀ yóo fi di ọgbà eléso,tí ọgbà eléso yóo sì fi di igbó.

Aisaya 32

Aisaya 32:13-20