Aisaya 32:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Wò ó! Ọba kan yóo jẹ pẹlu òdodo,àwọn ìjòyè yóo sì máa ṣe àkóso pẹlu ẹ̀tọ́.

2. Olukuluku yóo dàbí ibi ààbò nígbà tí ẹ̀fúùfù bá ń fẹ́ati ibi ìsásí nígbà tí ìjì bá ń jàWọ́n óo dàbí odò ninu aṣálẹ̀,ati bí ìbòòji àpáta ńlá nílẹ̀ olóoru.

Aisaya 32