Aisaya 31:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ní ọjọ́ náà, olukuluku yóo gbé àwọn ère fadakaati ère wúrà tí ó fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe sọnù,àwọn ère tí ó mú wọn dẹ́ṣẹ̀.

Aisaya 31

Aisaya 31:1-9