Ní ọjọ́ iwájúJakọbu yóo ta gbòǹgbò,Israẹli yóo tanná, yóo rúwé,yóo so, èso rẹ̀ yóo sì kún gbogbo ayé.