Aisaya 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìrẹ̀wẹ̀sì yóo dé bá àwọn ará Ijipti,n óo sọ ète wọn di òfo.Wọn yóo lọ máa wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ àwọn oriṣa ati àwọn aláfọ̀ṣẹati lọ́dọ̀ àwọn abókùúsọ̀rọ̀, ati àwọn oṣó.

Aisaya 19

Aisaya 19:2-6