Aisaya 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo fìyà jẹ àwọn ará Ijipti ṣugbọn yóo wò wọ́n sàn, wọn yóo pada sọ́dọ̀ OLUWA, yóo gbọ́ adura wọn, yóo sì wò wọ́n sàn.

Aisaya 19

Aisaya 19:21-25