Aisaya 11:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Èèhù kan yóo sọ jáde láti inú kùkùté igi Jese,ẹ̀ka kan yóo sì yọ jáde láti inú àwọn gbòǹgbò rẹ̀